Beta/Nightly | WordPress.org Yorùbá
WordPress.org

Beta/Nightly

Àwọn Beta Version Tí Kò Dúró Ṣinṣin

Tí o bá mọ PHP dáadáa tí o sì fẹ́ kópa nínú apá testing ti ìgbà development wa àti ròyìn àwọn bug tí o rí, àwọn beta release lè wà fún ọ.

Nítorí irú wọn, àwọn release wọ̀nyí kò dúró ṣinṣin, kò sì yẹ kí a lò wọ́n níbikíbi tí data rẹ ṣe pàtàkì. Jọ̀wọ́ ṣe backup database rẹ kí o tó ṣe upgrade sí beta release. Láti gbọ́ nípa àwọn beta release tuntun, ọ̀nà tó dára jù ni láti máa wo development blog àti beta forum.

O lè rí àwọn beta release tuntun lórí ojú ìwé Beta Releases.

Nightly Build

Development WordPress ń lọ ní kíákíá, àwọn nǹkan ojoojúmọ́ sì ń bàjẹ́ bí wọ́n ṣe ń tún wọn ṣe. Ìyípadà gíga yìí jẹ́ apá ìlànà development wa tó ń fojúsùn láti ṣẹ̀dá àwọn release tó dúró ṣinṣin jù lọ tó ṣeé ṣe.

Tí o bá fẹ́ jẹ́ apá ìlànà yìí, ibi tó dára jù láti bẹ̀rẹ̀ ni Beta Testing Handbook.